Skip to content

Ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu ati ẹni ti ẹjẹ ìbímọ n da lara rẹ, ǹjẹ́ wọn maa jẹun tabi mu ni ọsan Ramadan bi?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Ẹni ti o n ṣe nnkan oṣu ati ẹni ti ẹjẹ ìbímọ n da lara rẹ, ǹjẹ́ wọn maa jẹun tabi mu ni ọsan Ramadan bi?

س11: الحائض والنّفساء هل تأكلان وتشربان في نهار رمضان؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Bẹẹni, wọn maa jẹun wọn si maa mu ni ọsan Ramadan, ṣugbọn eyi ti o daa julọ ni ki o jẹ ni kọkọ ti ẹnikẹni ninu awọn ọmọde ba wa ni ọdọ rẹ ninu ile; nitori pe iyẹn maa da iruju sílẹ̀ fun wọn.

ج11: نعم، تأكلان وتشربان في نهار رمضان، لكن الأولى أن يكون ذلك سرًّا إذا كان عندها أحدٌ من الصّبيان في البيت؛ لأن ذلك يوجب إشكالًا عندهم.