"Mo fi Ẹni ti ẹmi Muhammad n bẹ lọwọ Rẹ bura, ẹnikẹni ko nii gbọ́ nipa mi ninu ìjọ yìí, Juu ni tabi Nasara, lẹyin naa o wa ku ti ko si ni igbagbọ pẹlu nnkan ti wọn fi ran mi, afi ko wa ninu awọn ara ina".
- التصنيف الشرعي
- العقيدةالأديانالأديان السماويةالعقيدةالإيمان بالرسلالإيمان بنبينا محمد صلى الله عليه وسلم
Lati ọdọ Abu Huraira- ki Ọlọhun yọnu si i- lati ọdọ ojiṣẹ Ọlọhun- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- o sọ pe:
"Mo fi Ẹni ti ẹmi Muhammad n bẹ lọwọ Rẹ bura, ẹnikẹni ko nii gbọ́ nipa mi ninu ìjọ yìí, Juu ni tabi Nasara, lẹyin naa o wa ku ti ko si ni igbagbọ pẹlu nnkan ti wọn fi ran mi, afi ko wa ninu awọn ara ina".
«وَالَّذِي نَفْسُ مُحَمَّدٍ بِيَدِهِ لَا يَسْمَعُ بِي أَحَدٌ مِنْ هَذِهِ الْأُمَّةِ يَهُودِيٌّ وَلَا نَصْرَانِيٌّ، ثُمَّ يَمُوتُ وَلَمْ يُؤْمِنْ بِالَّذِي أُرْسِلْتُ بِهِ إِلَّا كَانَ مِنْ أَصْحَابِ النَّارِ».
Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n bura pẹlu Ọlọhun pe ẹnikẹni ko nii gbọ́ nipa oun ninu ìjọ yìí, Juu ni tabi Nasara tabi ẹni ti o yatọ si awọn mejeeji, ti ipepe Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- de etiigbọ rẹ, lẹyin naa o wa ku ti ko si ni igbagbọ ninu rẹ afi ki o wa ninu awọn ara ina ti o maa ṣe gbere nibẹ lailai.
Kikari ìránṣẹ́ Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- si gbogbo aye, ati pe itẹle rẹ jẹ dandan, ati pipa gbogbo àwọn ofin rẹ pẹlu Sharia rẹ.
Ẹni ti o ba ṣe aigbagbọ si Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ini adisọkan igbagbọ rẹ pẹlu ẹni ti o yàtọ̀ si i ninu awọn Anabi- ki ikẹ Ọlọhun maa ba wọn patapata- ko nii ṣe e ni anfaani.
Ẹni ti ko ba gbọ nipa Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-, ti ipepe Isilaamu ko si de etiigbọ rẹ, oun jẹ ẹni ti o ni àwíjàre, alamọri rẹ ni ọrun si wa lọwọ Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga-.
Ṣíṣe anfaani pẹlu Isilaamu maa wa si ìmúṣẹ koda ki o jẹ pe o ku diẹ ti eeyan maa ku, koda ki o jẹ ninu aarẹ ti o le koko, niwọn igba ti ẹmi ko ba i tii de ọna ọfun.
Titun ẹsin awọn alaigbagbọ ṣe- ti Juu ati Nasara n bẹ ninu wọn- jẹ aigbagbọ.
Didarukọ Juu ati Nasara- ninu hadiisi náà- jẹ itaniji fun ẹni ti o yàtọ̀ si wọn; ìyẹn rí bẹ́ẹ̀ nitori pe iwe n bẹ fun Juu ati Nasara, ti ọrọ wọn ba wa ri báyìí, a jẹ pe ẹni tí o yàtọ̀ si wọn ti iwe ko si fun wọn ni ẹtọ si i ju wọn lọ, ati pe gbogbo wọn, wiwọ inu ẹsin rẹ jẹ dandan fun wọn ati itẹle rẹ- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a-.
Tira Sọhiihu ti Muslim (1/ 134) (153).
Tira Sọhiihu ti Muslim (1/ 134) (153).
Àlékún (10)
شرح النووي على مسلم (2/ 186).
الإفصاح عن معاني الصحاح.
لابن هبيرة (8/ 192).
طرح التثريب في شرح التقريب.
لعبد الرحيم العراقي (7/ 159).
شرح النووي على مسلم (2/ 186).
الإفصاح عن معاني الصحاح.
لابن هبيرة (8/ 192).
طرح التثريب في شرح التقريب.
لعبد الرحيم العراقي (7/ 159).
A tọ́ka sí nínú àwọn ìwé
10 Àwọn Ìwé- المنهج الوجيــز1<<Mo fi ẹni ti ẹmi Muhammad n bẹ lọwọ Rẹ bura, ẹnikẹni ko nii gbọ nípa mi ninu ijọ yii, Júù lo jẹ ni tabi Kristẹni, lẹyin naa ni o wa ku, ti ko si gbagbọ pẹlu nnkan ti wọn fi ran mi, afi ki o wa ninu awọn ero ina>>
- نبذة في العقيدة الإسلامية (شرح أصول الإيمان)نبذة في العقيدة الإسلامية“Mo fi ẹni ti ẹmi Muhammad n bẹ lọwọ Rẹ bura, ẹnikẹni ko nii gbọ nípa mi ninu ijọ yii, Júù lo jẹ ni tabi Kristẹni, lẹyin naa ni o wa ku, ti ko si gbagbọ pẹlu nnkan ti wọn fi ran mi, afi ki o wa ninu awọn ero ina”.
Àlékún (8)
- الأسئلة المختارة من قاموس الأسئلة الشائعة حول الإسلامقسم النبوة«وَالَّذِي نَفْسُ مُحَمَّدٍ بِيَدِهِ، لَا يَسْمَعُ بِي أَحَدٌ مِنْ هَذِهِ الْأُمَّةِ يَهُودِيٌّ وَلَا نَصْرَانِيٌّ، ثُمَّ يَمُوتُ وَلَمْ يُؤْمِنْ بِالَّذِي أُرْسِلْتُ بِهِ، إِلَّا كَانَ مِنْ أَصْحَابِ النَّارِ»
- الأسئلة المختارة من قاموس الأسئلة الشائعة حول الإسلامقسم القرآن والكتب السابقة«وَالَّذِي نَفْسُ مُحَمَّدٍ بِيَدِهِ لَا يَسْمَعُ بِي أَحَدٌ مِنْ هَذِهِ الْأُمَّةِ يَهُودِيٌّ وَلَا نَصْرَانِيٌّ ثُمَّ يَمُوتُ وَلَمْ يُؤْمِنْ بِالَّذِي أُرْسِلْتُ بِهِ إِلَّا كَانَ مِنْ أَصْحَابِ النَّارِ»
- الخطب المنبريةموسوعة الخطب المنبرية (القسم الأول)«وَالَّذِى نَفْسُ مُحَمَّدٍ بِيَدِهِ لَا يَسْمَعُ بِى أَحَدٌ مِنْ هَذِهِ الأُمَّةِ يَهُودِىٌّ وَلَا نَصْرَانِىٌّ ثُمَّ يَمُوتُ وَلَمْ يُؤْمِنْ بِالَّذِى أُرْسِلْتُ بِهِ إِلَّا كَانَ مِنْ أَصْحَابِ النَّارِ».
- عقيدة الأئمة الأربعة«وَالَّذِي نَفْسُ مُحَمَّدٍ بِيَدِهِ، لَا يَسمَعُ بِي أَحَدٌ مِنْ هَذِهِ الْأُمَّةِ يَهُودِيٌّ وَلَا نَصْرَانِيٌّ، ثُمَّ يَمُوتُ وَلَمْ يُؤْمِنْ بِالَّذِي أُرْسِلْتُ بِهِ، إِلَّا كَانَ مِنْ أَصْحَابِ النَّارِ»
- موسوعة الأسئلة (المجموعة الأولى)«وَالَّذِي نَفْسُ مُحَمَّدٍ بِيَدِهِ، لَا يَسْمَعُ بِي أَحَدٌ مِنْ هَذِهِ الْأُمَّةِ يَهُودِيٌّ وَلَا نَصْرَانِيٌّ، ثُمَّ يَمُوتُ وَلَمْ يُؤْمِنْ بِالَّذِي أُرْسِلْتُ بِهِ، إِلَّا كَانَ مِنْ أَصْحَابِ النَّارِ»
- موسوعة الأسئلة (المجموعة الأولى)«وَالَّذِي نَفْسُ مُحَمَّدٍ بِيَدِهِ لَا يَسْمَعُ بِي أَحَدٌ مِنْ هَذِهِ الْأُمَّةِ يَهُودِيٌّ وَلَا نَصْرَانِيٌّ ثُمَّ يَمُوتُ وَلَمْ يُؤْمِنْ بِالَّذِي أُرْسِلْتُ بِهِ إِلَّا كَانَ مِنْ أَصْحَابِ النَّارِ»
- نبراس طالب (4)1«وَالَّذِي نَفْسُ مُحَمَّدٍ بِيَدِهِ، لَا يَسْمَعُ بِي أَحَدٌ مِنْ هَذِهِ الْأُمَّةِ يَهُودِيٌّ وَلَا نَصْرَانِيٌّ، ثُمَّ يَمُوتُ وَلَمْ يُؤْمِنْ بِالَّذِي أُرْسِلْتُ بِهِ، إِلَّا كَانَ مِنْ أَصْحَابِ النَّارِ»
- نبراس طالب (5)1«وَالَّذِي نَفْسُ مُحَمَّدٍ بِيَدِهِ، لَا يَسْمَعُ بِي أَحَدٌ مِنْ هَذِهِ الْأُمَّةِ يَهُودِيٌّ وَلَا نَصْرَانِيٌّ، ثُمَّ يَمُوتُ وَلَمْ يُؤْمِنْ بِالَّذِي أُرْسِلْتُ بِهِ، إِلَّا كَانَ مِنْ أَصْحَابِ النَّارِ»