“Ko si igbeyawo kan afi pẹlu alaṣẹ obinrin”.
Lati ọdọ Abu Musa- ki Ọlọhun yọnu si i- dajudaju Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- sọ pé:
“Ko si igbeyawo kan afi pẹlu alaṣẹ obinrin”.
«لا نِكَاحَ إِلّا بِوَليٍّ».
Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- n ṣàlàyé pe dajudaju obìnrin, fifẹ rẹ ko lẹtọọ afi pẹlu alaṣẹ ti yoo ta koko igbeyawo náà.
لا نكاح : لا نكاح صحيح ومعتبر شرعًا.
الوَلِيُّ : هو أقرب الرجال إلى المرأة من عصبتها الذين يرثونها، كالأب والأخ.
Alaṣẹ obinrin jẹ majẹmu nibi nini alaafia igbeyawo, ti o ba waye laisi alaṣẹ obìnrin, tabi ti obìnrin ba fi ara rẹ lọkọ, igbeyawo naa ko ni alaafia.
Alaṣẹ obinrin ni ẹni ti o sunmọ obinrin julọ ninu awọn ọkunrin, nitori naa alaṣẹ obinrin ti o jina ko lee fi i lọkọ pẹlu bibẹ alaṣẹ obinrin ti o sunmọ.
Wọn ṣe ni majẹmu nibi alaṣẹ obinrin: Ijẹ ẹni tí o ti bàlágà, ati ijẹ ọkùnrin, ati imọna nibi mimọ awọn anfaani ìgbéyàwó, ki ẹsin alaṣẹ ati obìnrin jẹ bákannáà, ẹni ti ko ba ni awọn iroyin yii lara ko lẹtọọ si ijẹ alaṣẹ obinrin nibi tita koko igbeyawo.
Tira Sunanu ti baba Daud (3/ 427) (2085).
Tira Sunanu ti Tirmidhiy (2/ 392) (1101).
Tira Sunanu ti Ọmọ Maajah (3/ 79) (1881).
Tira Musnad ti Ahmad (32/ 280) (19518).
Àlékún (10)
البدرُ التمام شرح بلوغ المرام.
للمَغرِبي (7/ 57).
إرواء الغليل في تخريج أحاديث منار السبيل.
للألباني (6/ 237).
توضِيح الأحكام من بلوغ المَرَام.
للبسام (5/ 262).
منحة العلام في شرح بلوغ المرام.
لعبد الله الفوزان (7/ 222).
فتح ذي الجلال والإكرام بشرح بلوغ المرام.
لابن عثيمين (4/ 469).
A tọ́ka sí nínú àwọn ìwé
5 Àwọn ÌwéÀlékún (5)
- مجموعة زاد الفقه (4)«لا نِكاحَ إِلَّا بِوَليٍّ».
- مجموعة زاد الفقه (4)«لا نِكاحَ إِلَّا بِوَليٍّ وشاهِدَيْ عَدْلٍ».
- مشروع المنهج التعليميمادة الفقه مستوى 4:«لَا نِكَاحَ إِلَّا بِوَلِيٍّ»
- مشروع منهاج زادكزادك 3 طالب نهائي«لَا نِكَاحَ إِلَّا بِوَلِيٍّ وَشَاهِدَيْ عَدْلٍ»
- نبراس طالب (5)1«لَا نِكَاحَ إِلَّا بِوَلِيٍّ وَشَاهِدَيْ عَدْلٍ»