Skip to content
الأعرَاف /

Ẹsẹ 111

7 : 111

Ẹsẹ 111 of الأعرَاف (7 : 111). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

الأعرَاف Àwọn Ẹsẹ 206
Súrà · الأعرَاف
Yorùbá · Mikail
7 : 111

قَالُوٓاْ أَرۡجِهۡ وَأَخَاهُ وَأَرۡسِلۡ فِي ٱلۡمَدَآئِنِ حَٰشِرِينَ

Wọ́n sì wí pé: “Fún òun àti arákùnrin rẹ̀ lọ́jọ́, kí o sì rán àwọn akónijọ sí àwọn ìlú,

Explanation & meanings · 2
  1. Ọjọ́ ìpàdé náà ni ó jẹyọ nínú sūrah Tọ̄hā; 20:59.
  2. Àwọn ni àwọn ọlọ́pàá Fir‘aon.