Skip to content
Al-Mum'tahanah /

Ẹsẹ 5

60 : 5

Ẹsẹ 5 of Al-Mum'tahanah (60 : 5). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

Al-Mum'tahanah Àwọn Ẹsẹ 13
Súrà · Al-Mum'tahanah
Yorùbá · Mikail
60 : 5

رَبَّنَا لَا تَجۡعَلۡنَا فِتۡنَةٗ لِّلَّذِينَ كَفَرُواْ وَٱغۡفِرۡ لَنَا رَبَّنَآۖ إِنَّكَ أَنتَ ٱلۡعَزِيزُ ٱلۡحَكِيمُ

Olúwa wa, má ṣe wá ní àdánwò fún àwọn tó ṣàì gbàgbọ́. Foríjìn wá, Olúwa wa. Dájúdájú Ìwọ ni Alágbára, Ọlọ́gbọ́n.”

Explanation & meanings · 1
  1. Ìyẹn ni pé, má fi àwọn kèfèrí borí wa, kí ayé má fi lérò pé wọ́n wà lórí òdodo ni wọ́n fi borí wa.