Skip to content
Al-Qamar /

Ẹsẹ 2

54 : 2

Ẹsẹ 2 of Al-Qamar (54 : 2). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

Al-Qamar Àwọn Ẹsẹ 55
Súrà · Al-Qamar
Yorùbá · Mikail
54 : 2

وَإِن يَرَوۡاْ ءَايَةٗ يُعۡرِضُواْ وَيَقُولُواْ سِحۡرٞ مُّسۡتَمِرّٞ

Tí wọ́n bá rí àmì kan, wọ́n máa gbúnrí. Wọn yó sí wí pé: “Idán kan tó máa parẹ́ (ni èyí).”

Explanation & meanings · 1
  1. Ìtúmọ̀ mìíràn fún “sihrun mustamirr” idán kan tó lágbára (ni èyí).