Skip to content
An-Nisaa' /

Ẹsẹ 119

4 : 119

Ẹsẹ 119 of An-Nisaa' (4 : 119). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

An-Nisaa' Àwọn Ẹsẹ 176
Súrà · An-Nisaa'
Yorùbá · Mikail
4 : 119

وَلَأُضِلَّنَّهُمۡ وَلَأُمَنِّيَنَّهُمۡ وَلَأٓمُرَنَّهُمۡ فَلَيُبَتِّكُنَّ ءَاذَانَ ٱلۡأَنۡعَٰمِ وَلَأٓمُرَنَّهُمۡ فَلَيُغَيِّرُنَّ خَلۡقَ ٱللَّهِۚ وَمَن يَتَّخِذِ ٱلشَّيۡطَٰنَ وَلِيّٗا مِّن دُونِ ٱللَّهِ فَقَدۡ خَسِرَ خُسۡرَانٗا مُّبِينٗا

Dájúdájú mo máa ṣì wọ́n lọ́nà. Dájúdájú mo máa tàn wọ́n jẹ. Dájúdájú mo máa pa wọ́n láṣẹ, wọn yó sì máa gé etí ẹran-ọ̀sìn (láti yà á sọ́tọ̀ fún òrìṣà). Dájúdájú mo máa pa wọ́n láṣẹ, wọn yó sì máa yí ẹ̀sìn Allāhu padà.” Ẹnikẹ́ni tí ó bá mú aṣ-Ṣaetọ̄n ní ọ̀rẹ́ lẹ́yìn Allāhu, dájúdájú ó ti ṣòfò ní òfò pọ́nńbélé.

Explanation & meanings · 1
  1. Ìyẹn ni pé, aṣ-Ṣaetọ̄n yóò máa pa wọ́n ní àṣẹ pé kí wọ́n di kèfèrí àti ọ̀ṣẹbọ. Ẹ wo sūrah ar-Rūm; 30:30.