Skip to content
النِّسَاء /

Ẹsẹ 117

4 : 117

Ẹsẹ 117 of النِّسَاء (4 : 117). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

النِّسَاء Àwọn Ẹsẹ 176
4 : 117

إِن يَدۡعُونَ مِن دُونِهِۦٓ إِلَّآ إِنَٰثٗا وَإِن يَدۡعُونَ إِلَّا شَيۡطَٰنٗا مَّرِيدٗا

Wọn kò pe kiní kan lẹ́yìn Allāhu bí kò ṣe àwọn abo òrìṣà. Wọn kò sì pe kiní kan bí kò ṣe ṣaetọ̄n olùyapa.

Explanation & meanings · 1
  1. Nínú āyah yìí, “abo òrìṣà” túmọ̀ sí àwọn n̄ǹkan ọ̀bọrọgidi tí orúkọ wọn wá pẹ̀lú jẹ́ńdà abo tàbí àwọn orúkọ òrìṣà kan tí wọ́n wá pẹ̀lú jẹ́ńdà abo. Nítorí náà, abo òrìṣà kò túmọ̀ sí pé abo ni gbogbo àwọn òrìṣà ayé.