37 : 49
كَأَنَّهُنَّ بَيۡضٞ مَّكۡنُونٞ
Wọ́n dà bí ẹyin tí wọn kò ì bó èèpo rẹ̀ kúrò lára rẹ̀.
Explanation & meanings · 1
- Rírẹwà àwọn obìnrin Ọgbà Ìdẹ̀ra pọ̀ púpọ̀ tayọ òye ọmọnìyàn. Ìròyìn kan nìyẹn nínú rẹ̀.
Ẹsẹ 49 of الصَّافَات (37 : 49). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.
كَأَنَّهُنَّ بَيۡضٞ مَّكۡنُونٞ
Wọ́n dà bí ẹyin tí wọn kò ì bó èèpo rẹ̀ kúrò lára rẹ̀.