Skip to content
القَصَص /

Ẹsẹ 52

28 : 52

Ẹsẹ 52 of القَصَص (28 : 52). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

القَصَص Àwọn Ẹsẹ 88
Súrà · القَصَص
Yorùbá · Mikail
28 : 52

ٱلَّذِينَ ءَاتَيۡنَٰهُمُ ٱلۡكِتَٰبَ مِن قَبۡلِهِۦ هُم بِهِۦ يُؤۡمِنُونَ

Àwọn tí A fún ní Tírà ṣíwájú rẹ̀, wọ́n gbàgbọ́ nínú al-Ƙur’ān.