18 : 80
وَأَمَّا ٱلۡغُلَٰمُ فَكَانَ أَبَوَاهُ مُؤۡمِنَيۡنِ فَخَشِينَآ أَن يُرۡهِقَهُمَا طُغۡيَٰنٗا وَكُفۡرٗا
Ní ti ọmọdékùnrin náà, àwọn òbí rẹ̀ méjèèjì jẹ́ onígbàgbọ́ òdodo. A sì ń bẹ̀rù pé kí ó màa kó ìtayọ ẹnu-ààlà àti àìgbàgbọ́ bá àwọn méjèèjì.
Explanation & meanings · 1
- Ìyẹn ni pé, òbí ń ṣẹ Allāhu níbi ìfẹ́ ọmọ nígbà tí òbí bá ń pọ̀n lẹ́yìn ọmọ burúkú. Aburú ńlá sì ni fún àwọn méjèèjì.