Skip to content
الكَهف /

Ẹsẹ 11

18 : 11

Ẹsẹ 11 of الكَهف (18 : 11). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

الكَهف Àwọn Ẹsẹ 110
Súrà · الكَهف
Yorùbá · Mikail
18 : 11

فَضَرَبۡنَا عَلَىٰٓ ءَاذَانِهِمۡ فِي ٱلۡكَهۡفِ سِنِينَ عَدَدٗا

A kùn wọ́n l’óorun àsùnpiyè nínú ọ̀gbun àpáta f’ọ́dún gbọọrọ.