Skip to content
الحِجر /

Ẹsẹ 62

15 : 62
الحِجر Àwọn Ẹsẹ 99
Súrà · الحِجر
Yorùbá · Mikail
15 : 62

قَالَ إِنَّكُمۡ قَوۡمٞ مُّنكَرُونَ

(Ànábì Lūt) sọ pé: “Dájúdájú ẹ̀yin jẹ́ àjòjì ènìyàn.”