Skip to content
الرَّعد /

Ẹsẹ 43

13 : 43

Ẹsẹ 43 of الرَّعد (13 : 43). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

الرَّعد Àwọn Ẹsẹ 43
Súrà · الرَّعد
Yorùbá · Mikail
13 : 43

وَيَقُولُ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ لَسۡتَ مُرۡسَلٗاۚ قُلۡ كَفَىٰ بِٱللَّهِ شَهِيدَۢا بَيۡنِي وَبَيۡنَكُمۡ وَمَنۡ عِندَهُۥ عِلۡمُ ٱلۡكِتَٰبِ

Àwọn aláìgbàgbọ́ ń wí pé: “Ìwọ kì í ṣe Òjíṣẹ́.” Sọ pé: “Allāhu tó ní Ẹlẹ́rìí láààrin èmi àti ẹ̀yin àti ẹni tí ìmọ̀ Tírà ń bẹ lọ́dọ̀ (wọ́n tó ní ẹlẹ́rìí ) .”

Explanation & meanings · 1
  1. Ìyẹn ni pé, àwọn àlùfáà nínú àwọn yẹhudi àti nasọ̄rọ̄ mọ̀ pé àsọtọ́lẹ̀ nípa Ànábì Muhammad - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a - wà nínú tírà at-Taorāt àti al-’Injīl.