Skip to content

Nipa ṣíṣe aluwala latara nnkan ti o n sàn yẹn, njẹ fifọ awọn orikee aluwala nikan to bí?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Nipa ṣíṣe aluwala latara nnkan ti o n sàn yẹn, njẹ fifọ awọn orikee aluwala nikan to bí?

س42: بالنّسبة للوضوء من ذلك السائل، هل يكتفى بغسل أعضاء الوضوء فقط؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Bẹẹni, ìyẹn ti to ti o ba jẹ nnkan ti o mọ, oun ni eyi ti o n jade lati inu apo ìbímọ, ti ko kii ṣe lati inu apo itọ

ﺟ42: نعم، يكتفى بذلك فيما إذا كان طاهرًا، وهو الّذي يخرج من الرحم، لا من المثانة.