Skip to content
An-Naazihaat /

Ẹsẹ 43

79 : 43

Ẹsẹ 43 of An-Naazihaat (79 : 43). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

An-Naazihaat Àwọn Ẹsẹ 46
Súrà · An-Naazihaat
Yorùbá · Mikail
79 : 43

فِيمَ أَنتَ مِن ذِكۡرَىٰهَآ

Níbo ni ìwọ wà sí ìmọ̀ rẹ̀ ná?

Explanation & meanings · 1
  1. Ìyẹn ni pé, ìwọ kò lè ní ìmọ̀ ọjọ́ rẹ̀ ọjọ́ òpin ayé. Ọ̀dọ̀ Allāhu nìkan ṣoṣo ni ìmọ̀ rẹ̀ wà. Àmọ́ Allāhu fi àwọn àmì ìṣáájú ọjọ́ náà mọ Ànábì Rẹ̀ - kí ìkẹ́ àti ọlà Allāhu máa bá a -, ìyẹn ni àwọn àmì òpin ayé.