Skip to content
المُرسَلات /

Ẹsẹ 46

77 : 46
المُرسَلات Àwọn Ẹsẹ 50
77 : 46

كُلُواْ وَتَمَتَّعُواْ قَلِيلًا إِنَّكُم مُّجۡرِمُونَ

Ẹ jẹ, kí ẹ sì gbádùn fún ìgbà díẹ̀. Dájúdájú ẹlẹ́ṣẹ̀ ni yín.