Skip to content
المُدثر /

Ẹsẹ 17

74 : 17

Ẹsẹ 17 of المُدثر (74 : 17). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

المُدثر Àwọn Ẹsẹ 56
Súrà · المُدثر
Yorùbá · Mikail
74 : 17

سَأُرۡهِقُهُۥ صَعُودًا

Èmi yóò la ìyà pọ́nkèpọ́nkè bọ̀ ọ́ lọ́rùn (nínú Iná).

Explanation & meanings · 1
  1. Orúkọ àpáta ńlá kan nínú Iná ni Sọ‘ūd. Kèfèrí yóò máa pọ́n òkè náà láààrin àádọ́rin ọdún ní àpọ́njábọ́. Ìdí nìyí tí wọ́n fi pe ìyà náà ní ìyà pọ́nkèpọ́nkè.