Skip to content
الحَاقة /

Ẹsẹ 25

69 : 25

Ẹsẹ 25 of الحَاقة (69 : 25). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

الحَاقة Àwọn Ẹsẹ 52
Súrà · الحَاقة
Yorùbá · Mikail
69 : 25

وَأَمَّا مَنۡ أُوتِيَ كِتَٰبَهُۥ بِشِمَالِهِۦ فَيَقُولُ يَٰلَيۡتَنِي لَمۡ أُوتَ كِتَٰبِيَهۡ

Ní ti ẹni tí wọ́n bá sì fún ní tírà rẹ̀ ní ọwọ́ òsì rẹ̀, ó máa wí pé: “Háà! Kí wọ́n sì má fún mi ni tírà mi!

Explanation & meanings · 1
  1. Aláìgbàgbọ́ máa tì ọwọ́ òsì rẹ̀ bọ inú igbá-àyà rẹ̀ bọ́ sí ẹ̀yìn rẹ̀ láti fi gba ìwé iṣẹ́ rẹ̀.