Skip to content
الأنعَام /

Ẹsẹ 149

6 : 149
الأنعَام Àwọn Ẹsẹ 165
Súrà · الأنعَام
Yorùbá · Mikail
6 : 149

قُلۡ فَلِلَّهِ ٱلۡحُجَّةُ ٱلۡبَٰلِغَةُۖ فَلَوۡ شَآءَ لَهَدَىٰكُمۡ أَجۡمَعِينَ

Sọ pé: “Ti Allāhu ni ẹ̀rí tó dópin.” Nítorí náà, tí Ó bá fẹ́ ni, ìbá fi gbogbo yín mọ̀nà pátápátá.”

Explanation & meanings · 1
  1. Ẹ̀rí tó dópin ni ẹ̀rí apayànjẹ (ẹ̀rí tó ń pa iyàn jíjà jẹ), ẹ̀rí tó dé ògòńgó.