Skip to content
الذَّاريَات /

Ẹsẹ 28

51 : 28

Ẹsẹ 28 of الذَّاريَات (51 : 28). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

الذَّاريَات Àwọn Ẹsẹ 60
51 : 28

فَأَوۡجَسَ مِنۡهُمۡ خِيفَةٗۖ قَالُواْ لَا تَخَفۡۖ وَبَشَّرُوهُ بِغُلَٰمٍ عَلِيمٖ

Nígbà náà, ìbẹ̀rù wọn sì mú un.. Wọ́n sọ pé: “Má ṣe páyà.” Wọ́n sì fún un ní ìró ìdùnnú nípa bíbí ọmọkùnrin kan tí ó máa ní ìmọ̀.

Explanation & meanings · 1
  1. Tàbí “ó pa ìbẹ̀rù wọn mọ́ra”.