44 : 59
فَٱرۡتَقِبۡ إِنَّهُم مُّرۡتَقِبُونَ
Nítorí náà, máa retí. Dájúdájú àwọn náà ń retí.
Explanation & meanings · 1
- Ìyẹn ni pé, máa retí ìparun àwọn agbọ́mágbà.
Ẹsẹ 59 of الدُّخان (44 : 59). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.
فَٱرۡتَقِبۡ إِنَّهُم مُّرۡتَقِبُونَ
Nítorí náà, máa retí. Dájúdájú àwọn náà ń retí.