Skip to content
Ad-Dukhaan /

Ẹsẹ 33

44 : 33

Ẹsẹ 33 of Ad-Dukhaan (44 : 33). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

Ad-Dukhaan Àwọn Ẹsẹ 59
Súrà · Ad-Dukhaan
Yorùbá · Mikail
44 : 33

وَءَاتَيۡنَٰهُم مِّنَ ٱلۡأٓيَٰتِ مَا فِيهِ بَلَٰٓؤٞاْ مُّبِينٌ

A sì fún wọn ní àwọn àmì tí àdánwò pọ́nńbélé wà nínú rẹ̀.