Skip to content
سَبإ /

Ẹsẹ 29

34 : 29

Ẹsẹ 29 of سَبإ (34 : 29). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

سَبإ Àwọn Ẹsẹ 54
Súrà · سَبإ
Yorùbá · Mikail
34 : 29

وَيَقُولُونَ مَتَىٰ هَٰذَا ٱلۡوَعۡدُ إِن كُنتُمۡ صَٰدِقِينَ

Wọ́n ń wí pé: “Ìgbà wo ni àdéhùn yìí yóò ṣẹ tí ẹ bá jẹ́ olódodo?”