Skip to content
السَّجدة /

Ẹsẹ 29

32 : 29

Ẹsẹ 29 of السَّجدة (32 : 29). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

السَّجدة Àwọn Ẹsẹ 30
Súrà · السَّجدة
Yorùbá · Mikail
32 : 29

قُلۡ يَوۡمَ ٱلۡفَتۡحِ لَا يَنفَعُ ٱلَّذِينَ كَفَرُوٓاْ إِيمَٰنُهُمۡ وَلَا هُمۡ يُنظَرُونَ

Sọ pé: “Ní Ọjọ́ Ìdájọ́, ìgbàgbọ́ tí àwọn ọ̀ṣẹbọ máa fẹ́ ní nígbà tí wọ́n bá fojú rí ìyà Iná kò níí ṣe wọ́n ní àǹfààní. A kò sì níí lọ́ wọn lára láti ronúpìwàdà.”.”

Explanation & meanings · 1
  1. Irú āyah yìí ni sūrah al-’An‘ām; 6:158.