Skip to content
الكَهف /

Ẹsẹ 87

18 : 87

Ẹsẹ 87 of الكَهف (18 : 87). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

الكَهف Àwọn Ẹsẹ 110
Súrà · الكَهف
Yorùbá · Mikail
18 : 87

قَالَ أَمَّا مَن ظَلَمَ فَسَوۡفَ نُعَذِّبُهُۥ ثُمَّ يُرَدُّ إِلَىٰ رَبِّهِۦ فَيُعَذِّبُهُۥ عَذَابٗا نُّكۡرٗا

(Thul-Ƙọrnaen) sọ pé: “Ní ti ẹni tí ó bá ṣàbòsí, láìpẹ́ a máa jẹ ẹ́ níyà. Lẹ́yìn náà, wọn máa dá a padà sí ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ̀. Ó sì máa jẹ ẹ́ níyà tó burú.