Skip to content

Ti ẹni ti nnkan ti o n san jáde kelekele yẹn ba ṣe aluwala, ti o tun wa jáde lẹẹkan sii lẹ́yìn tí ó ti ṣe aluwala tan ṣiwaju ki o to kirun, ki ni o jẹ dandan fun un lati ṣe?

السؤال

Ibeere akọkọ:

Ti ẹni ti nnkan ti o n san jáde kelekele yẹn ba ṣe aluwala, ti o tun wa jáde lẹẹkan sii lẹ́yìn tí ó ti ṣe aluwala tan ṣiwaju ki o to kirun, ki ni o jẹ dandan fun un lati ṣe?

س40: إذا توضأت من ينزل منها ذلك السائل متقطّعًا، وبعد انتهائها من الوضوء وقبل صلاتها نزل مرةً أخرى، فماذا عليها؟

الجواب

Idahun akọkọ:

Ti o ba maa n ṣe ṣegeṣege, ki o ṣe sùúrù titi ti akoko ti o maa n dá nibẹ fi maa wọlé, ṣugbọn ti ko ba si iṣesi kan ti o han fun un, igba mii yoo jade, igba mii ko nii jade, nigba naa yoo maa ṣe aluwala lẹyin wiwọle akoko irun, yoo si kirun, ti nnkankan ko si jẹ dandan fun un lati ṣe.

ﺟ40: إذا كان متقطّعًا فلتنتظر حتى يأتي الوقت الذي ينقطع فيه، أما إذا كان ليس له حالٌ بيّنةٌ، حينًا ينزل، وحينًا لا، فهي تتوضأ بعد دخول الوقت، وتصلّي، ولا شيء عليها.