Skip to content
الأعرَاف /

Ẹsẹ 175

7 : 175

Ẹsẹ 175 of الأعرَاف (7 : 175). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

الأعرَاف Àwọn Ẹsẹ 206
Súrà · الأعرَاف
Yorùbá · Mikail
7 : 175

وَٱتۡلُ عَلَيۡهِمۡ نَبَأَ ٱلَّذِيٓ ءَاتَيۡنَٰهُ ءَايَٰتِنَا فَٱنسَلَخَ مِنۡهَا فَأَتۡبَعَهُ ٱلشَّيۡطَٰنُ فَكَانَ مِنَ ٱلۡغَاوِينَ

Ka ìròyìn ẹni tí A fún ní àwọn āyah Wa fún wọn, tí ó yọra rẹ̀ sílẹ̀ níbi àwọn āyah náà. Nítorí náà, aṣ-Ṣaetọ̄n tẹ̀lé e lẹ́yìn. Ó sì wà nínú àwọn olùṣìnà.

Explanation & meanings · 1
  1. Ó pa ìmọ̀ tì bí ìgbà tí ejò bá bọ́ ìhọ rẹ̀ sílẹ̀.