Skip to content
الذَّاريَات /

Ẹsẹ 46

51 : 46
الذَّاريَات Àwọn Ẹsẹ 60
51 : 46

وَقَوۡمَ نُوحٖ مِّن قَبۡلُۖ إِنَّهُمۡ كَانُواْ قَوۡمٗا فَٰسِقِينَ

Àti ìjọ Nūh tí ó ṣíwájú (wọn), dájúdájú wọ́n jẹ́ ìjọ arúfin.