50 : 24
أَلۡقِيَا فِي جَهَنَّمَ كُلَّ كَفَّارٍ عَنِيدٖ
Ẹ̀yin mọlāika méjèèjì, ẹ ju gbogbo aláìgbàgbọ́ olóríkunkun sínú iná Jahanamọ.
Explanation & meanings · 1
- Ìyẹn, olùdarí kan àti ẹlẹ́rìí kan nínú àwọn mọlāika.
Ẹsẹ 24 of قٓ (50 : 24). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.
أَلۡقِيَا فِي جَهَنَّمَ كُلَّ كَفَّارٍ عَنِيدٖ
Ẹ̀yin mọlāika méjèèjì, ẹ ju gbogbo aláìgbàgbọ́ olóríkunkun sínú iná Jahanamọ.