Skip to content
النِّسَاء /

Ẹsẹ 148

4 : 148

Ẹsẹ 148 of النِّسَاء (4 : 148). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

النِّسَاء Àwọn Ẹsẹ 176
4 : 148

۞ لَّا يُحِبُّ ٱللَّهُ ٱلۡجَهۡرَ بِٱلسُّوٓءِ مِنَ ٱلۡقَوۡلِ إِلَّا مَن ظُلِمَۚ وَكَانَ ٱللَّهُ سَمِيعًا عَلِيمًا

Allāhu kò nífẹ̀ẹ́ sí ariwo ọ̀rọ̀ burúkú (láti ọ̀dọ̀ ẹnikẹ́ni) àyàfi ẹni tí wọ́n bá ṣe àbòsí sí. Allāhu sì ń jẹ́ Olùgbọ́, Onímọ̀.

Explanation & meanings · 1
  1. Bíi sísọ àbòsí náà síta, sísọ̀rọ̀ sí alábòsí náà àti ṣíṣẹ́ èpè fún un ní ìbámu sí irú àbòsí náà. Ẹni tí ó bá ṣe bẹ́ẹ̀ ti gbẹ̀san nìyẹn ní ìbámu sí sūrah aṣ-Ṣūrọ̄; 42:41.