Skip to content
An-Nisaa' /

Ẹsẹ 137

4 : 137

Ẹsẹ 137 of An-Nisaa' (4 : 137). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

An-Nisaa' Àwọn Ẹsẹ 176
Súrà · An-Nisaa'
Yorùbá · Mikail
4 : 137

إِنَّ ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ ثُمَّ كَفَرُواْ ثُمَّ ءَامَنُواْ ثُمَّ كَفَرُواْ ثُمَّ ٱزۡدَادُواْ كُفۡرٗا لَّمۡ يَكُنِ ٱللَّهُ لِيَغۡفِرَ لَهُمۡ وَلَا لِيَهۡدِيَهُمۡ سَبِيلَۢا

Dájúdájú àwọn tó gbàgbọ́, lẹ́yìn náà wọ́n ṣàì gbàgbọ́, lẹ́yìn náà wọ́n gbàgbọ́, lẹ́yìn náà wọ́n ṣàì gbàgbọ́, lẹ́yìn náà wọ́n sì lékún sí i nínú àìgbàgbọ́, Allāhu kò níí forí jìn wọ́n, kò sì níí fí ọ̀nà mọ̀ wọ́n.

Explanation & meanings · 1
  1. Āyah yìí àti āyah 48 àti 116 fi rinlẹ̀ fún wa pé, kò sí àforíjìn fún ẹnikẹ́ni tí ó bá kú sínú àìgbàgbọ́ ńlá àti ìṣẹbọ ńlá sí Allāhu - subhānahu wa ta‘ālā -