Skip to content
الشعراء /

Ẹsẹ 89

26 : 89
الشعراء Àwọn Ẹsẹ 227
Súrà · الشعراء
Yorùbá · Mikail
26 : 89

إِلَّا مَنۡ أَتَى ٱللَّهَ بِقَلۡبٖ سَلِيمٖ

Àyàfi ẹni tí ó bá dé ọ̀dọ̀ Allāhu pẹ̀lú ọkàn mímọ́.”

Explanation & meanings · 1
  1. Ọkàn mímọ́ ni ọkàn tí ó là kúrò nínú ẹbọ ṣíṣe, àìgbàgbọ́ àti ìṣọ̀bẹ-ṣèlu nínú ẹ̀sìn.