Skip to content
Al-Fur'qaan /

Ẹsẹ 54

25 : 54

Ẹsẹ 54 of Al-Fur'qaan (25 : 54). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

Al-Fur'qaan Àwọn Ẹsẹ 77
Súrà · Al-Fur'qaan
Yorùbá · Mikail
25 : 54

وَهُوَ ٱلَّذِي خَلَقَ مِنَ ٱلۡمَآءِ بَشَرٗا فَجَعَلَهُۥ نَسَبٗا وَصِهۡرٗاۗ وَكَانَ رَبُّكَ قَدِيرٗا

Òun ni Ẹni tí Ó ṣẹ̀dá abara láti inú omi. Ó ṣe ìbátan ẹbí àti ìbátan àna fún un, Olúwa rẹ sì ń jẹ́ Alágbára.

Explanation & meanings · 1
  1. Ìṣẹ̀dá ènìyàn wáyé nípasẹ̀ oríṣi ọ̀nà mẹ́rin ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀. Ìkíní; nípasẹ̀ erùpẹ̀. Ìkejì; nípasẹ̀ ẹfọ́nhà. Ìkẹta; nípasẹ̀ omi àtọ̀. Ìkẹrin; nípasẹ̀ atẹ́gùn ẹ̀mí àti gbólóhùn “kunfayakūn” Rẹ̀.