Skip to content
Al-An'biyaa' /

Ẹsẹ 61

21 : 61

Ẹsẹ 61 of Al-An'biyaa' (21 : 61). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

Al-An'biyaa' Àwọn Ẹsẹ 112
Súrà · Al-An'biyaa'
Yorùbá · Mikail
21 : 61

قَالُواْ فَأۡتُواْ بِهِۦ عَلَىٰٓ أَعۡيُنِ ٱلنَّاسِ لَعَلَّهُمۡ يَشۡهَدُونَ

Wọ́n wí pé: “Ẹ mú un wá han àwọn ènìyàn kí wọ́n lè jẹ́rìí lé e lórí.”