Skip to content
قٓ /

Ẹsẹ 1

50 : 1

Ẹsẹ 1 of قٓ (50 : 1). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

قٓ Àwọn Ẹsẹ 45
Súrà · قٓ
Yorùbá · Mikail
50 : 1

قٓۚ وَٱلۡقُرۡءَانِ ٱلۡمَجِيدِ

Ƙọ̄f. (Allāhu ló mọ ohun tí Ó gbàlérò pẹ̀lú àwọn háràfí náà.) (Allāhu fi) al-Ƙur’ān alápọ̀n-ọ́nlé búra.

Explanation & meanings · 1
  1. Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ sūrah al Baƙọrah; 2:1.