Skip to content
النِّسَاء /

Ẹsẹ 21

4 : 21

Ẹsẹ 21 of النِّسَاء (4 : 21). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

النِّسَاء Àwọn Ẹsẹ 176
4 : 21

وَكَيۡفَ تَأۡخُذُونَهُۥ وَقَدۡ أَفۡضَىٰ بَعۡضُكُمۡ إِلَىٰ بَعۡضٖ وَأَخَذۡنَ مِنكُم مِّيثَٰقًا غَلِيظٗا

Báwo ni ẹ̀yin ṣe lè gbà á padà nígbà tí ó jẹ́ pé ẹ ti wọlé tọ’ra yín, tí wọ́n sì ti gba àdéhùn tó nípọn lọ́wọ́ yín!

Explanation & meanings · 1
  1. Àdéhùn tó nípọn tí ọkọ ṣe fún ìyàwó rẹ̀ ni pé, “Èmi yóò máa ṣe dáadáa pẹ̀lú rẹ̀ tàbí kí n̄g tú ọ sílẹ̀ pẹ̀lú dáadáa, ìyẹn tí ìkọ̀sílẹ̀ bá ṣẹlẹ̀.”