37 : 119 وَتَرَكۡنَا عَلَيۡهِمَا فِي ٱلۡأٓخِرِينَ A fún àwọn méjèèjì ní orúkọ rere láààrin àwọn ẹni ìkẹ́yìn.