Skip to content
آل عِمران /

Ẹsẹ 46

3 : 46

Ẹsẹ 46 of آل عِمران (3 : 46). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

آل عِمران Àwọn Ẹsẹ 200
3 : 46

وَيُكَلِّمُ ٱلنَّاسَ فِي ٱلۡمَهۡدِ وَكَهۡلٗا وَمِنَ ٱلصَّٰلِحِينَ

Ó máa bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ lórí ìtẹ́ ní òpóǹló àti nígbà tó bá dàgbà. Ó sì wà nínú àwọn ẹni rere.”

Explanation & meanings · 1
  1. Gẹ́gẹ́ bí ọmọdé kan ní àsìkò Juraej àti ọmọdé kan mìíràn ṣe sọ̀rọ̀ lórí ìtẹ́ ní òpóǹló.”