Skip to content
An-Nam'l /

Ẹsẹ 69

27 : 69

Ẹsẹ 69 of An-Nam'l (27 : 69). This page carries the verse in the Uthmani script with a translation of its meaning, at a stable URL that can be cited on its own.

An-Nam'l Àwọn Ẹsẹ 93
Súrà · An-Nam'l
Yorùbá · Mikail
27 : 69

قُلۡ سِيرُواْ فِي ٱلۡأَرۡضِ فَٱنظُرُواْ كَيۡفَ كَانَ عَٰقِبَةُ ٱلۡمُجۡرِمِينَ

Sọ pé: “Ẹ rìn kiri lórí ilẹ̀, kí ẹ wo bí àtubọ̀tán àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ṣe rí.”